Naira Marley - Soapy Lyrics | FAST DOWNLOAD

Soapy

O t`ẹsẹ`le bọ
Yahoo ni babalawo (Yahoo ni babalawo)
Ole l`everybody
Ẹni ilẹ mọ ba ṣa ni barawo
(Barawo, barawo, barawo)
(Mọ ba ṣa ni barawo)
O tẹsẹ`le bọ (O tẹsẹ`le bọ)
Yahoo ni babalawo (Yahoo ni babalawo)
Ole l`everybody
Ẹni ilẹ mọ ba ṣa ni barawo
O fẹ ṣe`ka fun mi (O fẹ ṣe`ka fun mi)
Mi o l`ogun mo ni Kurani (mo ni Kurani)
Mo dẹ n ṣ`adura mi
Bi m á¹£e n á¹£`adura mi
Allah n gba`dura mi (Allah n gba`dura mi)
A ti lọ a ti de (A ti lọ a ti de)
Ẹni ori yọ o di`le (Ẹni ori yọ o di`le)
Ẹni ba lọ l`o ba de
Igba ti m pada de
N`ṣe l`ọn de mi l`ade (N`ṣe l`ọn de mi l`ade)
K`ade ko pẹ l`ori (K`ade ko pẹ l`ori)
Ki bata k`o pe l`ẹsẹ (Ki bata k`o pe l`ẹsẹ)
K`awọn ọta mi kan l`ẹsẹ
Inside life (Inside)
O ti ri 5 Alive (O ti ri 5 Alive)
Inside life (Inside)
O ti ri Deeper Life (O ti ri Deeper Life)
Inside life
Awọn kan n jẹ`ya
Awọn kan n chop life
(Inside life) Inside life
Awọn kan n ṣ`epe
Awọn kan n jẹ`wa
Jo soapy, soapy
Kirikiri n jo soapy (Kirikiri n jo soapy)
Jo soapy, soapy
Ikoyi prison n jo soapy (Ikoyi prison n jo soapy)
Jo soapy
Ninu cell EFCC wọn n jo soapy (wọn n jo soapy)
Jo soapy
T`o o ba ni`yawo n`le k`o jo soapy
(Soapy!) soapy, soapy
Bọda yi n jo soapy (Bọda yi n jo soapy)
Soapy (Soapy)
Ab`ẹyin naa soapy? (Ab`ẹyin naa soapy?)
Soapy (Soapy)
Single father n jo soapy (Single father n jo soapy)
Soapy, ma lọ lo OMO t`o ba lọ n soapy (Soapy!)
Ṣ`o d`owo mọ? (Ṣ`o d`owo mọ?)
O wa sọ p`o o mọ Naira (O wa sọ p`o o mọ Naira)
O wuwo l`ọwọ
Iwọ ṣaa ṣẹ si Naira (Iwọ ṣaa ṣẹ si Naira)
Aja fẹ de`na d`ẹkun
Kekere ẹkun o ma n s`ẹgbẹ aja (ko n ṣ`ẹgbẹ aja)
Wọn n bẹ ni, Ma fọ
Awọn naa o fẹ wahala (Awọn naa o fẹ wahala)
I just wanna make Mama proud (I just wanna make Mama proud)
They want to make Mama cry
Mama you gonna cry no more
T`ẹ ba sun`kun gan ẹ o sọ`kun ayọ (ẹ o sọ`kun ayọ)
Ti m ba n jo k`ẹ ba m yọ (k`ẹ ba m yọ)
K`ọrọ mi ja s`ayọ (K`ọrọ mi ja s`ayọ)
Inside life, Inside life
Do a one course, it`s my life (Ku`onbẹ!)
Inside life (Inside)
O ti ri 5 Alive (O ti ri 5 Alive)
Inside life (Inside)
O ti ri Deeper Life (O ti ri Deeper Life)
Inside life
Awọn kan n jẹ`ya
Awọn kan n chop life
(Inside life) Inside life
Awọn kan n ṣ`epe
Awọn kan n jẹ`wa
Jo soapy, soapy
Kirikiri n jo soapy (Kirikiri n jo soapy)
Jo soapy, soapy
Ikoyi prison n jo soapy (Ikoyi prison n jo soapy)
Jo soapy
Ninu cell EFCC wọn n jo soapy (wọn n jo soapy)
Jo soapy
T`o o ba ni`yawo n`le k`o jo soapy
(Soapy!) soapy, soapy
Bọda yi n jo soapy (Bọda yi n jo soapy)
Soapy (Soapy)
Ab`ẹyin naa soapy? (Ab`ẹyin naa soapy?)
Soapy (Soapy)
Single father n jo soapy (Single father n jo soapy)
Soapy, ma lọ lo OMO t`o ba lọ n soapy
(Soapy!)

Date Added: 2020-05-22
Comments
0 (1 votes)
Artist Information
Newest Lyrics